Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni

Ayah by Ayah

Tags

Download Links

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni translation for Surah Al-Ma'un — Ayah 4

107:4
فَوَيۡلٞ لِّلۡمُصَلِّينَ ٤
Ègbé ni fún àwọn (mùnááfìkí) tó ń kírun;1
Footnotes
  • [1] Pẹ̀lú ìrun wákàtí márààrún lójoojúmọ́ ní àsìkò rẹ̀, ó ti run gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ wẹẹrẹ dànù. Ìrònúpìwàdà àti ìtọrọ-àforíjìn l’ó máa run àwọn ẹ̀ṣẹ̀ ńláńlá dànù.