Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni

Ayah by Ayah

Tags

Download Links

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni translation for Surah Al-Hujurat — Ayah 4

49:4
إِنَّ ٱلَّذِينَ يُنَادُونَكَ مِن وَرَآءِ ٱلۡحُجُرَٰتِ أَكۡثَرُهُمۡ لَا يَعۡقِلُونَ ٤
Dájúdájú àwọn tó ń pè ọ́ láti ẹ̀yìn àwọn yàrá1, ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ wọn ni kò ṣe làákàyè.
Footnotes
  • [1] “Àwọn yàrá” dúró fún “òdidi ilé”. Ìyẹn ni pé, àwọn tí wọ́n ń lọgun pé Ànábì - kí ìkẹ́ àti ọlà Allāhu máa bá a - láti iwájú ilé rẹ̀ ní ìta.