Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni

Ayah by Ayah

Tags

Download Links

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni translation for Surah Qaf — Ayah 24

50:24
أَلۡقِيَا فِي جَهَنَّمَ كُلَّ كَفَّارٍ عَنِيدٖ ٢٤
Ẹ̀yin mọlāika méjèèjì,1 ẹ ju gbogbo aláìgbàgbọ́ olóríkunkun sínú iná Jahanamọ.
Footnotes
  • [1] Ìyẹn, olùdarí kan àti ẹlẹ́rìí kan nínú àwọn mọlāika.