Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni

Ayah by Ayah

Tags

Download Links

A translation of every ayah of the Quran in Yoruba.

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni translation for Surah At-Tur — Ayah 5

52:5
وَٱلسَّقۡفِ ٱلۡمَرۡفُوعِ ٥
Ó tún fi àjà tí wọ́n gbé sókè (ìyẹn, sánmọ̀) búra.