Resources
Tools
Docs
Community
FAQ
Github
Login
CMS
Resources
Tools
Docs
Credits
Community
FAQ
Github
Login
Developer Resources
Translations
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Ayah by Ayah
Tags
Translation
With footnotes
Yoruba
Download Links
Download simple.json
Download translation-with-footnote-tags.sqlite
Download translation-text-chunk.json
Download translation-with-footnote-tags.json
Download simple.sqlite
Download translation-with-inline-footnote.sqlite
Download translation-text-chunk.sqlite
Download translation-with-inline-footnote.json
Preview
Docs
Licence
A translation of every ayah of the Quran in Yoruba.
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni translation for Surah An-Najm — Ayah 1
Jump to Ayah
[]
← Previous
Next →
53:1
وَٱلنَّجۡمِ إِذَا هَوَىٰ ١
Allāhu fi gbólóhùn kọ̀ọ̀kan nínú al-Ƙur’ān alápọ̀n-ọ́nlé nígbà tí ó bá sọ̀kalẹ̀ láti ojú sánmọ̀ búra.
1
Footnotes
[1]
Ìtúmọ̀ kejì ni pé, Allāhu fi ìràwọ̀ nígbà tí ó bá wálẹ̀ (wọ̀ọ̀kùn ní ìdájí) búra. Àmọ́ ìtúmọ̀ àkọ́kọ́ ló súnmọ́ jùlọ ní ìbámu sí sàkánì rẹ̀ pẹ̀lú àwọn āyah tí ó tẹ̀lé e. Wòóore! Wọ́n ń pe gbólóhùn ẹyọ kọ̀ọ̀kan nínú al-Ƙur’ān ní “an-najm”. Wọ́n sì ń pe ìràwọ̀ ní “an-najm”. Kódà “ìtàkùn” náà ń jẹ́ “an-najm” nínú èdè Lárúbáwá.(Tafsīr ’Adwā’ul-bayān)
Loading…
Loading…