Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni

Ayah by Ayah

Tags

Download Links

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni translation for Surah Al-Waqi'ah — Ayah 40

56:40
وَثُلَّةٞ مِّنَ ٱلۡأٓخِرِينَ ٤٠
Wọ́n tún pọ̀ nínú àwọn ẹni Ìkẹ́yìn.1
Footnotes
  • [1] Àwọn ẹni àkọ́kọ́ dúró fún àwọn ènìyàn láti àsìkò Ànábì Ādam títí di àsìkò Ànábì ‘Īsā - kí ọlà Allāhu máa bá wọn -. Àwọn ẹni Ìkẹ́yìn sì dúró fún ìjọ Ànábì wa nìkan - kí ìkẹ́ àti ọlà Allāhu máa bá a -.