Resources
Tools
Docs
Community
FAQ
Github
Login
CMS
Resources
Tools
Docs
Credits
Community
FAQ
Github
Login
Developer Resources
Translations
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Ayah by Ayah
Tags
Translation
With footnotes
Yoruba
Download Links
Download simple.json
Download translation-with-footnote-tags.sqlite
Download translation-text-chunk.json
Download translation-with-footnote-tags.json
Download simple.sqlite
Download translation-with-inline-footnote.sqlite
Download translation-text-chunk.sqlite
Download translation-with-inline-footnote.json
Preview
Docs
Licence
A translation of every ayah of the Quran in Yoruba.
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni translation for Surah Al-Mulk — Ayah 14
Jump to Ayah
[]
← Previous
Next →
67:14
أَلَا يَعۡلَمُ مَنۡ خَلَقَ وَهُوَ ٱللَّطِيفُ ٱلۡخَبِيرُ ١٤
Ṣé kò mọ Ẹni tí Ó ṣẹ̀dá ni?
1
Òun sì ni Aláàánú, Alámọ̀tán.
Footnotes
[1]
Ìyẹn ni pé, tí ẹ̀dá bá lérò pé, bí òun bá sọ̀rọ̀ ní ìkọ̀kọ̀, ó yẹ kí ẹ̀dá náà mọ̀ dájú pé, nínú ìròyìn Ẹlẹ́dàá rẹ̀ ni pé, Ẹlẹ́dàá nímọ̀ èrò-ọkàn àwọn ẹ̀dá Rẹ̀, áḿbọ̀sìbọ́sí ọ̀rọ̀ tí àwọn ẹ̀dá Rẹ̀ sọ ní ìkọ̀kọ̀. Ìtúmọ̀ kejí: “Ṣé Allāhu kò mọ ẹni tí Ó ṣẹ̀dá ni?” Ìyẹn ni pé, ṣé Allāhu kò mọ àwọn ẹ̀dá Rẹ̀ tòhun tí ọ̀rọ̀ ìkọ̀kọ̀ wọn, ọ̀rọ̀ gban̄gba wọn àti èrò-ọkàn wọn? Allāhu mọ gbogbo rẹ̀.
Loading…
Loading…