Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni

Ayah by Ayah

Tags

Download Links

A translation of every ayah of the Quran in Yoruba.

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni translation for Surah Al-Qalam — Ayah 31

68:31
قَالُواْ يَٰوَيۡلَنَآ إِنَّا كُنَّا طَٰغِينَ ٣١
Wọ́n wí pé: “Ègbé wa ò! Dájúdájú àwa jẹ́ olùtayọ-ẹnu ààlà.