Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni

Ayah by Ayah

Tags

Download Links

A translation of every ayah of the Quran in Yoruba.

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni translation for Surah Al-Ma'arij — Ayah 41

70:41
عَلَىٰٓ أَن نُّبَدِّلَ خَيۡرٗا مِّنۡهُمۡ وَمَا نَحۡنُ بِمَسۡبُوقِينَ ٤١
láti yí (ìrísí wọn) padà (ní ọjọ́ Àjíǹde) sí (ìrísí kan) tó máa dára ju (ìrísí) wọn (tayé). Kò sì sí ẹni tó lè dá Wa lágara.1
Footnotes
  • [1] Ẹ tún wo sūrah al-Wāƙi‘ah; 56:60-61 àti sūrah al-Ƙiyāmọh; 75:3-4.