Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni

Ayah by Ayah

Tags

Download Links

A translation of every ayah of the Quran in Yoruba.

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni translation for Surah Al-Mutaffifin — Ayah 34

83:34
فَٱلۡيَوۡمَ ٱلَّذِينَ ءَامَنُواْ مِنَ ٱلۡكُفَّارِ يَضۡحَكُونَ ٣٤
Nítorí náà, ní òní àwọn tó gbàgbọ́ ní òdodo yóò fi àwọn aláìgbàgbọ́ rẹ́rìn-ín.